Gospel music minister and songwriter, Olawumi Esho drops a new single titled “Iye” (Breathe Of Life)”.
Inspired by the Holy Spirit, this song ‘Iye'(Breath of Life) passes the message of victories given to believers by God in Christ,thereby , strengthening the confidence and assurance the Breath of Life(Christ) gave to us at the point of salvation.
About Olawumi Esho
Esho Olawumi is a lover of God and a practicing Registered Nurse, who was born in Ibadan, the capital city of Oyo State.
She ministers the gospel through music and longs to see men coming into the kingdom of Abba.
Lyrics:
O ti fun mi ni iye
Iye ayeraye
Nipa ore ofe re
Lo fi fun mi
O si gba mi
O si gba mi o
Lowo ogun, ogun aye
Baba ti soro
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Olu orun lo soro yi o
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Baba ti fi mi lokanbale
Nipa ojo ola
O si fun mi ni ayo
Ayo ayeraye
O ti gba mi o lowo ogun,ogun aye
Baba ti soro
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Olu orun lo soro yi o
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Baba lo soro yi o
Nibi ikoko mi o wipe
Omo ma beru rara
For I will be with you and won’t forsake you
O si fun mi ni’ye ayeraye
He preserves me and restoreth my soul
Baba ti soro
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Olu orun lo soro yi o
O wipe o
Omo mo wa pelu re
Emi wa s’ibi abo Oluwa
Mo to o wa s’ibi imole ayeraye
Ipa ona re ni mo n to
Jesu ise igbala yi
Se ‘yebiye
Iyebiye loje
Iyebiye loje
Iyebiye loje
Iyebiye lo je
Iyebiye loje o
Iyebiye lo je
Iyeloye lo je o
Iyebiye lo je o
Connect With Olawumi Esho:
Twitter: @eshoolawumi
Imstagram: @officialeshoolawumi
0 Comments